Ojo Aiku, Sannde to koja yii bi agba olorin fuji naa subu lojiji, ti won gbe e digbadigba lo si ileewosan yii, sugbon ko laju titi ti elemi-in fi gba a laaaro yii. Omo bibi ilu Ibadan ni Sawaba, rekoodu kan to gbe jade logbon odun seyin to pe pata olokun lo so o di ilu mo on ka
Aaro oni ni agba-oje olorin Fuji nni, Alaaji Isiaka Iyanda Sawaba jade laye. Ileewosan ijoba UCH lokunrin naa dake si.

No comments:
Post a Comment