Kaakiri ibi gbogbo lawọn arugbo ti waa janfaani iwosan-ọfẹ, idanilẹkọọ, oogun oyinbo ati tibilẹ pẹlu jijẹ ati mimun ti wọn fun wọn nibi eto naa. Diẹ ninu awọn aworan ti wọn ya lọjọ naa ree.
Ọkan pataki ninu awọn gbajumọ sọrọsọrọ ori radio ati tẹlifiṣan ni, Ọtunba Tokunbọ Babs Olurinde Aderinoku ti gbogbo aye mọ si Skin Dudu. Laipẹ lobinrin naa ṣe eto iranwọ fawọn arugbo labẹ ajọ kan to da silẹ to pe ni Skin Dudu Aged Foundation.
Kaakiri ibi gbogbo lawọn arugbo ti waa janfaani iwosan-ọfẹ, idanilẹkọọ, oogun oyinbo ati tibilẹ pẹlu jijẹ ati mimun ti wọn fun wọn nibi eto naa. Diẹ ninu awọn aworan ti wọn ya lọjọ naa ree.
Kaakiri ibi gbogbo lawọn arugbo ti waa janfaani iwosan-ọfẹ, idanilẹkọọ, oogun oyinbo ati tibilẹ pẹlu jijẹ ati mimun ti wọn fun wọn nibi eto naa. Diẹ ninu awọn aworan ti wọn ya lọjọ naa ree.
No comments:
Post a Comment