Latowo Taofik Afolabi
Lati aaro anaa, lariwo naa ti n lo laarin igboro pe gomina ipinle Ekiti to n kopa wole bayii, Ogbeni Peter Ayodele Fayose fee fi egbe oselu PDP sile lo sinu egbe mi-in.
Ohun tawon kan tie so ni pe nitori awon EFCC ti n won dode e lokunrin naa se fee sa lo sinu egbe APC. Sugbon, Fayose ti soro, o ti so pe ko si ohun ti yoo gbe oun kuro ninu egbe PDP lo sinu egbe mi-in laelae, o ni titi aye loun yoo wa ninu egbe naa.
Alaye ti okunrin naa se ni pe oun yoo pawopo pelu oludije ipo aare labe egbe oselu PDP, Alaaji Atiku Abubakar gbajoba lowo Buhari lodun to n bo ni.
Pelu ohun ti Fayose, tawon mi-in tun maa n pe ni Oshokomole so yii, o ti fihan pe ko nibi kankan to n lo, o si wa digbi ninu egbe PDP.
Tuesday, 9 October 2018
Home
/
OSELU
/
EMI O NI I KURO NINU EGBE PDP LAELAE, MO MA PAWOPO PEU ATIKU GBAJOBA LOWO BUHARI NI-FAYOSE
EMI O NI I KURO NINU EGBE PDP LAELAE, MO MA PAWOPO PEU ATIKU GBAJOBA LOWO BUHARI NI-FAYOSE
Nipa IROYIN OJUTOLE
NJE O NI IROYIN FUN WA BI? TABI O NI AYEYE TI O FE KI A BA O GBE JADE? ABI IPOLOWO OJA TABI IKEDE LE FE SE, TETE PE SORI AWON NOMBA WONYI: 08023939928, 08185819080.
OSELU
Tags
OSELU
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
No comments:
Post a Comment