IROYIN YAJOYAJO

ipolowo

Monday 17 September 2018

'KO MO ON LO, E GBA A LOWO E, E GBE E FUN JIDE', ORIN TI WASIU AYINDE FI TA SI AMBODE NIYEN O

Gbogbo awon eeyan ti won saaba ma a n wa lori ero ayelujara ni won ti gbo orin kan ti gbajumo osere fuji nni, Alaaji Wasiu Ayinde ko to fi tabuku gomina ipinle Eko, Ogbeni Akinwumi Ambode.

Orin ohun ni K1 fi so fawon eeyan Eko pe ki won gbajoba kuro lowo Ambode, ki won gbe e fun Jide Sanwoolu ti Asiwaju Bola Ahmed Tinubu fa kale lati koju Ambode ninu abele egbe APC.

Orin naa lo ko bayii pe ' E gba  a lowo e, ko mo on lo,e gbe fun Jide, eni ba ju ni
lo, o le ju ni nu'. Orin yii lawon eeyan n ko kaakiri bayii.   

No comments:

Post a Comment

Adbox