Ojo nla ti alaga egbe awon abaniwale atawon to n ta ile ati ile ni gbogbo Owode-Ibeshe, Onarebu Bimbo Obademi Oladare ko ni i gbagbe lojo Abameta, Satide to koja yii. Ojo naa lokunrin naa sayeye ojoobi e. Bamubamu lawon eeyan pataki atawon omo egbe kun ibi ti ayeye naa ti waye.

Bi jije se po lopo yanturu, bee ni mimu naa kun ile bii eni, ti orin aladun naa lo ni melomelo
Eni to ba ri Onarebu Bimbo tawon ololufe e tun maa n pe ni Origo lojo yii, yoo mo pe inu e dun pupo lojo yii.













No comments:
Post a Comment